AMI OHUN

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Access detailed SS 2 Yoruba Language notes for the 1st, 2nd, and 3rd terms, covering key topics based on the current curriculum. These notes are ideal for students preparing for exams or seeking to improve their understanding of the subject.
See our comprehensive SS 2 Yoruba Language notes for 1st, 2nd, and 3rd terms. Perfect for exam preparation and revision.

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m…

Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n,…

Iro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa…

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke…

Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado.…

Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si. Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun, orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa…

AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe. A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo + kobo = kobokobo Odun + odun = odoodun Ale + …

Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.

Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo; O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si egbe wa. Baba Ramo…

AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Fun Apeere Wa-je oro onisilebu kan nitori pe…

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko…

A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a] faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e] faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε] faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese [i] faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese [o] faweli…

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade…
“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku ni ebun oro-siso. Bi apeere, ti a ba so wi…

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si ki o to lo si Oke Itase. Idi niyi ti…

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata…

ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan.…

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun…

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon ni: Oro ipinle; ati Oro ti a seda ORO IPINLE:…

Femi: Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo: Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi: Mo rii. O dun mi wonu…