AMI OHUN
Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o… Read More »AMI OHUN
Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o… Read More »AMI OHUN
Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni;… Read More »IRO KONSONANTI
Iro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa… Read More »IRO FAWELI
Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro,… Read More »EYA ARA IFO
Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo… Read More »ORUNMILA
Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si. Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun, orisa ni Olorun da won, won… Read More »AWON ORISA ILE YORUBA
AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe. A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo + … Read More »ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE
Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.
Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo; O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi… Read More »AYOKA ONISOROGBESI
AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa… Read More »ORI-ORO | SILEBU EDE YORUBA
Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo… Read More »AROKO AJEMO ISIPAYA
A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a] faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e] faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε] faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju… Read More »Didaruko Faweli
AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le… Read More »OSE KESAN-AN
“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO
ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA
Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA
ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa… Read More »AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA
Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO
AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon… Read More »OSE KERIN-IN
Femi: Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo: Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri… Read More »AARE BOOLU