Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)

Aroko atonisona asotan ni aroko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju wari tabi awon ise ti a gbo lenu enikan Ilana Fun Kiko Aroko Oniroyin Koko oro:- Eyi ni oro oro aroko Ero:- Akekoo gbodo…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions

Aroko atonisona asotan ni aroko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju wari tabi awon ise ti a gbo lenu enikan Ilana Fun Kiko Aroko Oniroyin Koko oro:- Eyi ni oro oro aroko Ero:- Akekoo gbodo…

AKOLE ISE:- Ede:- Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori oro Aroso Asotan Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo…

Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe

Aroso alapejuwe ni sise apejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to sele gege bi a se rii g an-an pelu ohun enu. Aroso ni ki si ni akosile ohun enu ni a fi n se apejuwe isele naa. Apeere ori oro…

Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye) Ose keji: Ede aroso alapejuwe Asa-asa iranra-ero lowo Litireso-ewi alohun to je mo…

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional…

Eyan ni awon wunren (oro) ti a fi n yan oro – oruko (noun) tai apola oruko (Noun phrase) ninu gbolohun tabi ninu isori. Bi apeere: Iwe tuntun ni a f era Aso ala ni mo wo ‘Tuntun’ ati ‘ala’…

IGBESE LETA AIGBEFE Adiresi: Adiresi akoleta (The writer’s address) Adiresi agbaleta (Receiver’s address) Deeti (the day’s date) iii. Ikini ibeere (salutation) Akole leta (the tittle / heading) Koko leta (main content) Ikadii / ipari leta (conclusion) Leta aigbagbefe /…

Kin – in – ni awe gbolohun? Awe gbolohun ni ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se Bi apeere: Ayinke mu omi Adepoju ti jeun Kasali je eba Awe gbolohun le je ipede ti ko ni ju apola…

ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE) IGBESE IGBEYAWO ALAYE Ifojusode Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin. Iwadii Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu. Won yoo tun se, iwadi lowo ifa. Alarina Alarina…

Oge sise ni a n pe ni oso. Oso ara, oso ile. Ki a se itoju ara, aso, ile ni gbogbo e dale lori. Ki a se itoju irun: irun didi, irun gige, iwe wiwe, enu fifo, ara pipa/jija eekanna…

Ni aye ode-oni eto iselu ti yato patapata is ti aye atijo. Ni aye ode-oni, eto iselu ti aye ode-oni ni a n lo gomina ni Olori ati alase ni ilu kookan ti o si ni awon komisanna ti won…

Ipa ti baale ile, Iyaale-ile omobinrin ile, omokunrin ile, omo osu n ko ninu eto isakoso agbo ile ati ebi gbigboona. Eto iselu ni ile Yoruba bere lati inu ile, gege bi asa ,baba ni Olori ile, iya ni…

IHUN ORO (ISODORUKO) IGBESE Bi a se n seda oro oruko nipa lilo afomo ibere AKOONU:- Iseda oro-oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko eyi ni awon igbese…

Inu ede ti a ti n ya oro lo. Ona ti a n gba ya oro wonu ede Yoruba. Akoonu Oro – ayalo -: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede…

Foniimu konsonanti Foniimu faweli ati ohun Eda foniimu konsonanti ati faweli Akoonu (Iro aseyato) Foniimu ni awon iro ti o le fi iyato han laaarin oro kan tabi omiran Ap Foniimu ni /b/ /d/ /t/, eyi ti o tumo si…

ORIKI ORISII IPA TI WON N KO NI AWUJO AKOONU Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won. Ni aye atijo,iwonba…

AKOONU Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere: Ajayi: A-ja-yi = silebu meta Olabisi O-la-bi-si silebu merin. Adeleke A-de-le-ke silebu merin Olopaa O-lo-pa-a silebu merin Gbangbadekun gba-n-gba-de-kun silebu marun-un.…

Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo (…

Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi…