AMI OHUN

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m…
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions
Lesson Notes, Audio Lessons, Exam Questions

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m…

Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n,…

Iro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa…

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke…

Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado.…

Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si. Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun, orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa…

AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe. A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo + kobo = kobokobo Odun + odun = odoodun Ale + …

Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.

Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo; O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si egbe wa. Baba Ramo…

AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Fun Apeere Wa-je oro onisilebu kan nitori pe…

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko…

Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu (a) Oro apejuwe le yan oro – oruko ni ipo…

Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. Ise Oro-Oruko Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun – Oluwa ni oluse nnkan ninu gbolohun apeere; Ayinde ra aso…

Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re. Aroko oniroyin je aroko ti o jo mo iroyin sise. Eyi le je kiko sile tabi si so lenu. Awon Igbese/Ilara Kiko Aroko Oniroyin Mi…

Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun onibo/olo po oro-ise Gbolohun Abode/Ele yo oro-ise Gbolohun Abode je…

Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya gbolohun ti o wa ninu ede yoruba Gbolohun abode Gbolohun…

Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :- Awon awako n sare asa pajude loju…

Akaye: Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yei yekeyeke. Orisi ayoka ninu akaye Akaye oloro geere Akaye ewi Akaye oni isoro-n-gbesi Igbese Ti A Ni Lati Tele Ki Ayoka Le…

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti…

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012 Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT) Ona ti a le gba dena ogun Ki ife ti o gbona wa laarin awon ara ilu Ki asoye…